Baba wa

Baba wa ti mbẹ li ọrun.

Ki a bọwọ fun orukọ rẹ.      

Ki ijọba rẹ de.

Ifẹ tirẹ ni ki așe li aiye

Bi wọn ti nșe li ọrun

Fun wa ni onjẹ  ojọ wa loni

Dari ẹșẹ wa ji wa

Bi ati ndari ẹșẹ ji awọn

Ti oșẹ wa.Mafa wa sinu

Idanwo. șugbon gba wa lọwọ bilisi

Amin

Category:
Yoruba